Sauberfuss
Recent Posts
Connect with:
Monday / June 27.
HomeStandard Blog Whole Post – don’t delete this one too!

Igboho ní k’a dúpẹ́ l’ọ́wọ́ọ Ààrẹ Patrice Talon ti ìlúu Benin Republic

Àkọsẹ̀gbé Aiyé – Iba Gani Adams

 

The Ààrẹ delivered this speech during the Ifa Festival on Tuesday August 17, 2021

Iba Gani Adams pè fún àtìlẹ́hìn-in Sunday Igboho!

 

Prof Wole Soyinka on Sunday Igboho and Nnamdi Kanu

Our sincere apologies! 🙁

This video has been removed by YouTube.

Yoruba Obas connive with Tinubu to send Nigerian Army and DSS to attack Sunday Igboho

Sunday Igboho’s residence under heavy military bombardment – 2 killed already.

The greatest threat to freedom is the absence of criticism.

 

– Wole Soyinka

Sunday Igboho's residence under heavy military attack

(1) Èdèe Yorùbá ò jọ àwọn ọmọ Yoòbá l’ójú rárá!

(2) Yorùbá ní láti padà sí Ẹ̀sìn Ìṣẹ̀ṣe-Abínibíi wọn àtijọ́

Ñṣe l’ó dàbíipé àwọn bàbáa wa yī ti ka ñkan t’ã kọ l’óríi yorubatoday.com k’ọ́n t’ó sọ ọ̀rọ̀ t’ọ́n sọ n’ínúun fidio o wọn yī ni.

 

Àá mọ̀n’pé a rí ẹnìkan ṣoṣo n’ílẹ̀ẹ Yorùbá t’ó ñ ro’nú bí ilé iṣẹ́ẹ Yorùbá Today ṣe ń ro’nú.

 

Inúun wa dún sí ọ̀rọ̀ tí àwọ́n bàbá sọ yī gãn ni. Ẹyin nã ẹ gbe yẹ̀ wò!

 

Ẹ lè kọ́kọ́ ka eléyī k’ẹ t’ó wá gbádùn un fidio yī: On’ílé ò fun’ra pẹ̀lúu ìtumọ̀n ọ́n rẹ̀ ní èdèe Gẹ̀ẹ́sí

The greatest threat to freedom is the absence of criticism.

 

– Wole Soyinka

Yorùbá ní láti padà sí Ẹ̀sìn Ìṣẹ̀ṣe-Abínibíi

Professor Peter Fatomilọla, the veteran seasoned Nollywood actor, bears his thoughts on the state of the nation.

 

Yorùbá nation is the way forward. Ojú á k’ára!  We’ll be able to meet our leaders directly and talk with them.

The greatest threat to freedom is the absence of criticism.

 

– Wole Soyinka

Slavery

 

Remember when the white man carted away our brothers and sisters during slavery?

 

Upon getting to the plantation in the West Indies and the Americas where they were forced to labour, the white man drilled holes in both the upper and the lower lips of every slave and padlocked them, so they would not be able to eat the sugarcane and quench their thirst as they laboured in the scorching sun. This is exactly what is happening in Nigeria today.

 

Tí nwọ́n bá ní ẹnìkan ní Ijẹbu tàbí ará Ekiti kan l’ó n ṣ’olórí; tí aà bá fẹ́ nkan t’ó ń ṣe, àá lọ báa ní Ààfin Ààrẹ ni láti lọ fi ẹ̀dùn ọkàn-an wa hàn – nítorí èdè kan nã l’a jọ ń sọ! Ṣùgbọ́n ẹni t’óò gb’édèe ẹ̀, t’óò mọ̀n’wàa ẹ̀, t’óò mọ̀n’ran ẹ̀, t’óò mọ̀n’rìn-in ẹ̀, t’ó bá ń  da’rí ẹ, t’ó ń f’ìyà jẹ ẹ́, t’óò dẹ̀ r’ẹ́ni gbà ẹ́ s’ílẹ̀; ẹrú aiyéraiyé ni ẹ ẹ̀! O dẹ̀ mã ṣ’ẹrú kú ni!

 

Àwọn kan ń sọ pé ṣé Ilẹ̀ ẹ Yoòbá ò níí kó sí wàhálàa ọ̀rọ̀ ẹni t’ó ma ṣ’olórí fún wa n’ígbàt’ã bá gba Òmìnira ọ̀hún nã tán? – Ẹ̀yin ẹ jẹ́ k’a lé Akátá lọ ná, k’a t’ó f’àbọ̀ bá’dìẹ̀!

Quick appraisal of Europe

 

Whoever thinks Yorùbá region is too small to stand on their own, think again. Some of the countries below with their individual population stats have been quoted to make the average Yorùbá appreciate that the total population of Odùduwà land also falls among those countries. Yorùbá land is actually larger than many of these nations in our list.

 

In Europe, Austria (pop: 9 million) is governed by Austrian Germans; Belgium (pop: 11 million) is governed by Belgians; Croatia (pop: 4 million) is governed by Croats; Czech Republic (pop: 10 million) is governed by Czechs; England is governed by the English; France is governed by the French; Germany is governed by Germans; Italy is governed by Italians; the Netherlands (17 million) is governed by the Dutch; Greece (pop: 10 million) is governed by Greeks; Hungary (pop: 9 million) is governed by Hungarians; Poland (pop: 38 million) is governed by Poles; even Romania (pop: 19 million) is governed by the Romanians; Russia is governed by Russians; Spain (pop: 47 million) is governed by Spaniards; Switzerland (pop: 8 million) is governed by the Swiss.

 

In Africa, these tiny countries and municipalities readily come to mind: Benin Republic, Togo, Gambia, Burkina Faso, Cameroon; even Ghana, to name just a few. The proposed Yorùbá republic is larger than anyone of these countries.

Professor Peter Fatomilọla, the veteran seasoned Nollywood

Selfless warriors only come once in our lifetime. The king of Shomolu-Bariga is enjoining us all to support the man God is using at the moment to fight the cause of the Yorùbá people. “We should not betray him, even if we don’t support him,” the king beseeches Odùduwà citizens.

 

The king reckons restructuring is way too late for Nigeria, a.k.a. Location 9.

 

A rather long while back, circa in the 1970s perhaps, the idea was posited that every state in the country should go their separate ways, and utilize materials indigenous to every state. Talk about “trial and error”.

 

Thankfully, all the states of the federation were and still are abound in natural resources as well as human talent and skills; yet the federal government would not heed. Today, everyone seems to have realized that the best way forward for the country is federalism after all.

 

Ọba Gbolahan Timson of Shomolu-Bariga in Lagos state says “the matter is beyond redemption; it’s past using force to keep the regions together.”

 

“The way I would like us to approach this is not to resort to arming ourselves and killing people,” the king advises.

Let us all support Sunday Igboho and

Nwọ́n ní Ẹ̀rín ni Àgbà Oògùn…

Ẹ sinmi díẹ̀ k’a d’ẹ́rīn pa yín, k’ára yín tú díẹ̀ n’ínúu rògbòdìyàn-an Covid-19 yī!

Ẹ lè wá bá wa pín-in fún àwọn ọ̀rẹ́ àti ojúlùmọ̀n-ọ́n yín gbogbo.

Ẹ ṣe’un, a dúpẹ́ l’ọ́pọ̀lọpọ̀… 🙂

The greatest threat to freedom is the absence of criticism.

– Wole Soyinka.

Mannequin Scare

Watch the baby!

Donec quam felis, ultricies nec, pellentesque eu,

Lagos metropolis

The greatest threat to freedom is the absence of criticism.

– Wole Soyinka

Try not to become a man of success. Rather, become a man of value.

– Albert Einstein

[vc_row css=".vc_custom_1458549864192{padding-top: 43px !important;padding-left: 10% !important;}"][vc_column][vc_column_text]Lagos metropolis[/vc_column_text][/vc_column][/vc_row][vc_row

error: Gb’ọ́wọ́ ẹ !!