Sauberfuss
Recent Posts
Connect with:
Thursday / October 6.
HomeAwarenessYorùbá ro’nú!

Yorùbá ro’nú!

(1) Èdèe Yorùbá ò jọ àwọn ọmọ Yoòbá l’ójú rárá!

(2) Yorùbá ní láti padà sí Ẹ̀sìn Ìṣẹ̀ṣe-Abínibíi wọn àtijọ́

Ñṣe l’ó dàbíipé àwọn bàbáa wa yī ti ka ñkan t’ã kọ l’óríi yorubatoday.com k’ọ́n t’ó sọ ọ̀rọ̀ t’ọ́n sọ n’ínúun fidio o wọn yī ni.

 

Àá mọ̀n’pé a rí ẹnìkan ṣoṣo n’ílẹ̀ẹ Yorùbá t’ó ñ ro’nú bí ilé iṣẹ́ẹ Yorùbá Today ṣe ń ro’nú.

 

Inúun wa dún sí ọ̀rọ̀ tí àwọ́n bàbá sọ yī gãn ni. Ẹyin nã ẹ gbe yẹ̀ wò!

 

Ẹ lè kọ́kọ́ ka eléyī k’ẹ t’ó wá gbádùn un fidio yī: On’ílé ò fun’ra pẹ̀lúu ìtumọ̀n ọ́n rẹ̀ ní èdèe Gẹ̀ẹ́sí

The greatest threat to freedom is the absence of criticism.

 

– Wole Soyinka

No comments

leave a comment

error: Gb’ọ́wọ́ ẹ !!